Jóòbù 42:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O sọ pé, ‘Ta lẹni yìí tí kò jẹ́ kí ìmọ̀ràn mi ṣe kedere, tí kò ní ìmọ̀?’+ Torí náà, mo sọ̀rọ̀, àmọ́ mi ò lóye,Nípa àwọn ohun tó yà mí lẹ́nu gidigidi, tí mi ò mọ̀.+
3 O sọ pé, ‘Ta lẹni yìí tí kò jẹ́ kí ìmọ̀ràn mi ṣe kedere, tí kò ní ìmọ̀?’+ Torí náà, mo sọ̀rọ̀, àmọ́ mi ò lóye,Nípa àwọn ohun tó yà mí lẹ́nu gidigidi, tí mi ò mọ̀.+