ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 14:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ṣé kò yé ìkankan lára àwọn oníwà burúkú ni?

      Wọ́n ń ya àwọn èèyàn mi jẹ bí ẹni ń jẹ búrẹ́dì.

      Wọn ò ké pe Jèhófà.

  • Òwe 22:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ẹni tó ń lu aláìní ní jìbìtì láti túbọ̀ kó ọrọ̀ jọ+

      Àti ẹni tó ń fún ọlọ́rọ̀ lẹ́bùn

      Yóò di aláìní.

  • Àìsáyà 32:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ohun búburú ni ọkùnrin oníwàkíwà ń gbèrò;+

      Ìwà àìnítìjú ló ń gbé lárugẹ,

      Kó lè fi irọ́ ba ti ẹni tí ìyà ń jẹ jẹ́,+

      Kódà nígbà tí aláìní bá ń sọ ohun tó tọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́