Òwe 23:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Fetí sí bàbá rẹ tó bí ọ lọ́mọ,Má sì pa ìyá rẹ tì torí pé ó ti darúgbó.+