Òwe 27:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹlòmíì* ni kó yìn ọ́, kì í ṣe ẹnu tìrẹ;Àwọn míì* ni kó ṣe bẹ́ẹ̀, kì í ṣe ètè ìwọ fúnra rẹ.+