-
Oníwàásù 10:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ẹ wo bó ṣe máa jẹ́ ohun ayọ̀ tó fún ilẹ̀ náà, tí ọba rẹ̀ bá jẹ́ ọmọ èèyàn pàtàkì, tí àwọn ìjòyè rẹ̀ sì ń jẹun ní àkókò tí ó tọ́ kí wọ́n lè lágbára, kì í ṣe kí wọ́n lè mutí yó!+
-