-
Diutarónómì 28:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Jèhófà máa pàṣẹ ìbùkún sórí àwọn ilé ìkẹ́rùsí+ rẹ àti gbogbo ohun tí o bá dáwọ́ lé, ó sì dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa bù kún ọ ní ilẹ̀ tó fẹ́ fún ọ.
-
-
Sáàmù 4:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 O ti fi ayọ̀ púpọ̀ kún ọkàn mi
Ju ti àwọn tó ní ọ̀pọ̀ ọkà àti wáìnì tuntun nígbà ìkórè.
-