- 
	                        
            
            Jóòbù 3:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Kí ló dé tí mi ò kú nígbà tí wọ́n bí mi? Kí ló dé tí mi ò ṣègbé nígbà tí mo jáde látinú ikùn?+ 
 
- 
                                        
11 Kí ló dé tí mi ò kú nígbà tí wọ́n bí mi?
Kí ló dé tí mi ò ṣègbé nígbà tí mo jáde látinú ikùn?+