Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ 1 Sámúẹ́lì 22:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìgbà náà ni ọba sọ fún Dóẹ́gì+ pé: “Ìwọ, lọ pa àwọn àlùfáà náà!” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Dóẹ́gì ọmọ Édómù+ lọ pa àwọn àlùfáà náà fúnra rẹ̀. Ọkùnrin márùnlélọ́gọ́rin (85) tó ń wọ éfódì+ tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe ni ó pa lọ́jọ́ yẹn.
8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+
18 Ìgbà náà ni ọba sọ fún Dóẹ́gì+ pé: “Ìwọ, lọ pa àwọn àlùfáà náà!” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Dóẹ́gì ọmọ Édómù+ lọ pa àwọn àlùfáà náà fúnra rẹ̀. Ọkùnrin márùnlélọ́gọ́rin (85) tó ń wọ éfódì+ tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe ni ó pa lọ́jọ́ yẹn.