Jóòbù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ló dé tí àwọn ẹni burúkú ṣì fi wà láàyè,+Tí wọ́n ń darúgbó, tí wọ́n sì ń di ọlọ́rọ̀?*+ Sáàmù 73:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí ọ̀rọ̀ àwọn ẹni burúkú ṣe rí nìyí, àwọn tí gbogbo nǹkan dẹrùn fún.+ Wọ́n ń kó ọrọ̀ jọ ṣáá.+