Sáàmù 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+ Òwe 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Òmùgọ̀ ló ń da ẹ̀bi rẹ̀* sáwàdà,+Àmọ́ àwọn adúróṣinṣin máa ń fẹ́ láti pa dà wà níṣọ̀kan.*
14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+