Diutarónómì 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ibẹ̀ ni kí ẹ̀yin àti àwọn agbo ilé yín ti jẹun níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ sì máa yọ̀ nínú gbogbo ohun tí ẹ bá dáwọ́ lé,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ti bù kún yín. Sáàmù 104:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àti wáìnì tó ń mú ọkàn èèyàn yọ̀,+Òróró tó ń mú kí ojú dánÀti oúnjẹ tó ń gbé ẹ̀mí ẹni kíkú ró.+ Oníwàásù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+
7 Ibẹ̀ ni kí ẹ̀yin àti àwọn agbo ilé yín ti jẹun níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ sì máa yọ̀ nínú gbogbo ohun tí ẹ bá dáwọ́ lé,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ti bù kún yín.
24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+