Òwe 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ọgbọ́n ni aláròjinlẹ̀ fi ń lóye ibi tí ọ̀nà rẹ̀ máa já sí,Àmọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ àwọn òmùgọ̀ ló ń ṣì wọ́n lọ́nà.*+ Òwe 17:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àǹfààní wo ló jẹ́ fún òmùgọ̀ pé ó rí ọ̀nà láti ní ọgbọ́nNígbà tí kò ní làákàyè?*+
8 Ọgbọ́n ni aláròjinlẹ̀ fi ń lóye ibi tí ọ̀nà rẹ̀ máa já sí,Àmọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ àwọn òmùgọ̀ ló ń ṣì wọ́n lọ́nà.*+