Jóòbù 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+ Lúùkù 12:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí náà, ẹ yéé wá ohun tí ẹ máa jẹ àti ohun tí ẹ máa mu, ẹ má sì jẹ́ kí àníyàn kó yín lọ́kàn sókè mọ́;+
14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+
29 Torí náà, ẹ yéé wá ohun tí ẹ máa jẹ àti ohun tí ẹ máa mu, ẹ má sì jẹ́ kí àníyàn kó yín lọ́kàn sókè mọ́;+