Sáàmù 37:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa ṣe rere;+Máa gbé ayé,* kí o sì máa hùwà òtítọ́.+ 1 Tẹsalóníkà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni ò fi búburú san búburú fún ẹnì kankan,+ kí ẹ sì máa fìgbà gbogbo wá ohun rere fún ara yín àti fún gbogbo àwọn míì.+
15 Ẹ rí i pé ẹnikẹ́ni ò fi búburú san búburú fún ẹnì kankan,+ kí ẹ sì máa fìgbà gbogbo wá ohun rere fún ara yín àti fún gbogbo àwọn míì.+