Jeremáyà 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, ìwọ Ọba àwọn orílẹ̀-èdè,+ nítorí ó yẹ bẹ́ẹ̀;Láàárín gbogbo ọlọ́gbọ́n tó wà ní àwọn orílẹ̀-èdè àti ní gbogbo ìjọba wọn,Kò sí ẹnì kankan tó dà bí rẹ.+ Ìfihàn 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”
7 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, ìwọ Ọba àwọn orílẹ̀-èdè,+ nítorí ó yẹ bẹ́ẹ̀;Láàárín gbogbo ọlọ́gbọ́n tó wà ní àwọn orílẹ̀-èdè àti ní gbogbo ìjọba wọn,Kò sí ẹnì kankan tó dà bí rẹ.+
4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”