31 Torí ó ti dá ọjọ́ kan tó máa fi òdodo ṣèdájọ́ + ayé láti ọwọ́ ọkùnrin kan tó ti yàn, ó sì ti pèsè ẹ̀rí tó dájú fún gbogbo èèyàn bó ṣe jí i dìde kúrò nínú ikú.”+
5 Àmọ́ nítorí agídí rẹ àti ọkàn rẹ tí kò ronú pìwà dà, ò ń kó ìrunú jọ sórí ara rẹ, ìrunú yìí máa hàn ní ọjọ́ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run.+6 Yóò san kálukú lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀:+