Òwe 6:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,+11 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+ Òwe 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọ̀lẹ kì í túlẹ̀ nígbà òtútù,Tó bá dìgbà ìkórè, á máa tọrọ torí pé kò ní nǹkan kan.*+
10 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,+11 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+