ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 20:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Má ṣe nífẹ̀ẹ́ oorun, torí wàá di aláìní.+

      La ojú rẹ, wàá sì máa jẹ àjẹtẹ́rùn.+

  • Òwe 24:33, 34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,

      Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,

      34 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,

      Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+

  • Oníwàásù 4:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Òmùgọ̀ ká ọwọ́ gbera, bẹ́ẹ̀ ló ń rù sí i.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́