Jẹ́nẹ́sísì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Kò dáa kí ọkùnrin náà máa dá wà. Màá ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tó máa jẹ́ ẹnì kejì rẹ̀.”+ Òwe 27:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bí irin ṣe ń pọ́n irin,Bẹ́ẹ̀ ni èèyàn ṣe ń pọ́n* ọ̀rẹ́ rẹ̀.+
18 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Kò dáa kí ọkùnrin náà máa dá wà. Màá ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tó máa jẹ́ ẹnì kejì rẹ̀.”+