Orin Sólómọ́nì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Olólùfẹ́ mi dà bí egbin, bí akọ ọmọ àgbọ̀nrín.+ Òun nìyẹn, ó dúró sí ẹ̀yìn ògiri wa,Ó ń yọjú lójú fèrèsé,* Ó ń yọjú níbi àwọn fèrèsé tó ní asẹ́ onígi. Orin Sólómọ́nì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Títí afẹ́fẹ́ yóò fi bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ́,* tí òjìji kò sì ní sí mọ́,Tètè pa dà, ìwọ olólùfẹ́ mi,Bí egbin+ tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín+ lórí àwọn òkè tó yà wá sọ́tọ̀.*
9 Olólùfẹ́ mi dà bí egbin, bí akọ ọmọ àgbọ̀nrín.+ Òun nìyẹn, ó dúró sí ẹ̀yìn ògiri wa,Ó ń yọjú lójú fèrèsé,* Ó ń yọjú níbi àwọn fèrèsé tó ní asẹ́ onígi.
17 Títí afẹ́fẹ́ yóò fi bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ́,* tí òjìji kò sì ní sí mọ́,Tètè pa dà, ìwọ olólùfẹ́ mi,Bí egbin+ tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín+ lórí àwọn òkè tó yà wá sọ́tọ̀.*