- 
	                        
            
            Òwe 27:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Òróró àti tùràrí máa ń mú ọkàn yọ̀; Bẹ́ẹ̀ ni adùn ọ̀rẹ́ máa ń wá látinú ìmọ̀ràn àtọkànwá.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Mo dìde kí n lè ṣílẹ̀kùn fún olólùfẹ́ mi; Òjíá ń kán tótó ní ọwọ́ mi, Òjíá olómi ń kán ní àwọn ìka mi, Sára ọwọ́ ilẹ̀kùn. 
 
-