1 Sámúẹ́lì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ni Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù bá lọ sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hóréṣì, ó sì ràn án lọ́wọ́ kí ó lè túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà.+ Òwe 15:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Inú èèyàn máa ń dùn tí ìdáhùn rẹ̀ bá tọ̀nà,*+Ọ̀rọ̀ tó bá sì bọ́ sí àkókò mà dára o!+ Òwe 16:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọ̀rọ̀ dídùn jẹ́ afárá oyin,Ó dùn mọ́ ọkàn,* ó sì ń wo egungun sàn.+
16 Ni Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù bá lọ sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hóréṣì, ó sì ràn án lọ́wọ́ kí ó lè túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà.+