- 
	                        
            
            Jeremáyà 48:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        28 Ẹ fi àwọn ìlú sílẹ̀, kí ẹ sì lọ máa gbé lórí àpáta, ẹ̀yin tó ń gbé ní Móábù, Kí ẹ sì dà bí àdàbà tó kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àfonífojì.’” 
 
-