Orin Sólómọ́nì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Lórí ibùsùn mi ní òru,Mo wá ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́.*+ Mo wá a, àmọ́ mi ò rí i.+