Orin Sólómọ́nì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo ṣílẹ̀kùn fún olólùfẹ́ mi,Àmọ́ olólùfẹ́ mi ti pa dà, ó ti lọ. Àfi bíi pé kò sí ìrètí fún mi* nígbà tó lọ.* Mo wá a, ṣùgbọ́n mi ò rí i.+ Mo pè é, àmọ́ kò dá mi lóhùn.
6 Mo ṣílẹ̀kùn fún olólùfẹ́ mi,Àmọ́ olólùfẹ́ mi ti pa dà, ó ti lọ. Àfi bíi pé kò sí ìrètí fún mi* nígbà tó lọ.* Mo wá a, ṣùgbọ́n mi ò rí i.+ Mo pè é, àmọ́ kò dá mi lóhùn.