Orin Sólómọ́nì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Lórí ibùsùn mi ní òru,Mo wá ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́.*+ Mo wá a, àmọ́ mi ò rí i.+ Orin Sólómọ́nì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn tó ń ṣọ́ ìlú rí mi nígbà tí wọ́n ń lọ yí ká.+ Mo bi wọ́n pé, ‘Ṣé ẹ bá mi rí olólùfẹ́ mi?’*