2 Sámúẹ́lì 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà náà, Dáfídì tu Bátí-ṣébà+ ìyàwó rẹ̀ nínú. Ó wọlé lọ bá a, ó sì bá a ní àṣepọ̀. Nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sólómọ́nì.*+ Jèhófà sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ Òwe 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọmọ gidi ni mo jẹ́ fún bàbá mi+Ìyá mi sì fẹ́ràn mi lọ́nà àrà ọ̀tọ̀.+
24 Nígbà náà, Dáfídì tu Bátí-ṣébà+ ìyàwó rẹ̀ nínú. Ó wọlé lọ bá a, ó sì bá a ní àṣepọ̀. Nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sólómọ́nì.*+ Jèhófà sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+