-
Orin Sólómọ́nì 6:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Olólùfẹ́ mi ti lọ sí ọgbà rẹ̀,
Síbi ebè tí wọ́n gbin àwọn ewé tó ń ta sánsán sí,
Kó lè tọ́jú àwọn àgùntàn nínú ọgbà,
Kó sì já àwọn òdòdó lílì.+
-