Àìsáyà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó dájú pé ó máa yọ ìtànná;+Ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa kígbe ayọ̀. A máa fún un ní ògo Lẹ́bánónì,+Ẹwà Kámẹ́lì+ àti ti Ṣárónì.+ Wọ́n máa rí ògo Jèhófà, ẹwà Ọlọ́run wa.
2 Ó dájú pé ó máa yọ ìtànná;+Ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa kígbe ayọ̀. A máa fún un ní ògo Lẹ́bánónì,+Ẹwà Kámẹ́lì+ àti ti Ṣárónì.+ Wọ́n máa rí ògo Jèhófà, ẹwà Ọlọ́run wa.