-
Orin Sólómọ́nì 7:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ọmú rẹ méjèèjì dà bí ọmọ àgbọ̀nrín méjì,
Ó dà bí ọmọ egbin tí wọ́n jẹ́ ìbejì.+
-
-
Orin Sólómọ́nì 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “Ògiri ni mí,
Ọmú mi sì dà bí ilé gogoro.
Lójú rẹ̀, mo ti wá dà bí
Ẹni tó ní àlàáfíà.
-