-
Orin Sólómọ́nì 2:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àwọn èso tó kọ́kọ́ yọ lórí igi ọ̀pọ̀tọ́ ti pọ́n;+
Àwọn àjàrà ti yọ òdòdó, wọ́n sì ń ta sánsán.
Dìde, olólùfẹ́ mi, máa bọ̀.
Arẹwà mi, tẹ̀ lé mi ká lọ.
-