ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 36:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Wò ó! A gbé Ọlọ́run ga nínú agbára rẹ̀;

      Olùkọ́ wo ló dà bíi rẹ̀?

      23 Ta ló ń darí ọ̀nà rẹ̀,*+

      Tàbí tó lè sọ fún un pé, ‘Ohun tí o ṣe ò dáa’?+

  • Róòmù 11:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Nítorí “ta ló mọ èrò Jèhófà,* ta sì ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?”+

  • 1 Kọ́ríńtì 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Nítorí “ta ló ti wá mọ èrò inú Jèhófà,* kí ó lè kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́?”+ Àmọ́ àwa ní èrò inú Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́