Àìsáyà 40:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ta ló ti díwọ̀n* ẹ̀mí Jèhófà,Ta ló sì lè dá a lẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?+ Dáníẹ́lì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+
35 Kò ka gbogbo àwọn tó ń gbé ayé sí nǹkan kan, ohun tó bá sì wù ú ló ń ṣe láàárín àwọn ọmọ ogun ọ̀run àti àwọn tó ń gbé ayé. Kò sí ẹni tó lè dá a dúró*+ tàbí kó sọ fún un pé, ‘Kí lo ṣe yìí?’+