Àìsáyà 44:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+ Àìsáyà 46:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá pe ẹyẹ aṣọdẹ wá láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Ọkùnrin tó máa ṣe ohun tí mo pinnu*+ máa wá láti ilẹ̀ tó jìn. Mo ti sọ̀rọ̀, màá sì mú kó ṣẹ. Mo ti ní in lọ́kàn, màá sì ṣe é.+ Ìfihàn 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìkẹfà da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú odò ńlá Yúfírétì,+ omi rẹ̀ sì gbẹ+ láti palẹ̀ ọ̀nà mọ́ fún àwọn ọba+ láti ibi tí oòrùn ti ń yọ.*
28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+
11 Màá pe ẹyẹ aṣọdẹ wá láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Ọkùnrin tó máa ṣe ohun tí mo pinnu*+ máa wá láti ilẹ̀ tó jìn. Mo ti sọ̀rọ̀, màá sì mú kó ṣẹ. Mo ti ní in lọ́kàn, màá sì ṣe é.+
12 Ìkẹfà da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú odò ńlá Yúfírétì,+ omi rẹ̀ sì gbẹ+ láti palẹ̀ ọ̀nà mọ́ fún àwọn ọba+ láti ibi tí oòrùn ti ń yọ.*