Àìsáyà 41:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ta ló ti gbé ẹnì kan dìde láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Tó pè é nínú òdodo wá síbi ẹsẹ̀ Rẹ̀,*Láti fa àwọn orílẹ̀-èdè lé e lọ́wọ́,Kó sì mú kó tẹ àwọn ọba lórí ba?+ Ta ló ń sọ wọ́n di eruku níwájú idà rẹ̀,Bí àgékù pòròpórò tí atẹ́gùn ń gbé kiri níwájú ọfà rẹ̀? Àìsáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
2 Ta ló ti gbé ẹnì kan dìde láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+Tó pè é nínú òdodo wá síbi ẹsẹ̀ Rẹ̀,*Láti fa àwọn orílẹ̀-èdè lé e lọ́wọ́,Kó sì mú kó tẹ àwọn ọba lórí ba?+ Ta ló ń sọ wọ́n di eruku níwájú idà rẹ̀,Bí àgékù pòròpórò tí atẹ́gùn ń gbé kiri níwájú ọfà rẹ̀?
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: