Jeremáyà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n dà bí aṣọ́komásùn tó wà nínú oko kùkúńbà,* wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Ńṣe là ń gbé wọn, torí wọn ò lè rìn.+ Má bẹ̀rù wọn, torí wọn ò lè pani lára,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ṣeni lóore kankan.”+
5 Wọ́n dà bí aṣọ́komásùn tó wà nínú oko kùkúńbà,* wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Ńṣe là ń gbé wọn, torí wọn ò lè rìn.+ Má bẹ̀rù wọn, torí wọn ò lè pani lára,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ṣeni lóore kankan.”+