Àìsáyà 57:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ta ló ń já ọ láyà, tí ẹ̀rù rẹ̀ sì ń bà ọ́,Tí o fi bẹ̀rẹ̀ sí í parọ́?+ O ò rántí mi.+ O ò fi nǹkan kan sọ́kàn.+ Ṣebí mo ti dákẹ́, tí mo sì fà sẹ́yìn?*+ O ò wá bẹ̀rù mi rárá.
11 Ta ló ń já ọ láyà, tí ẹ̀rù rẹ̀ sì ń bà ọ́,Tí o fi bẹ̀rẹ̀ sí í parọ́?+ O ò rántí mi.+ O ò fi nǹkan kan sọ́kàn.+ Ṣebí mo ti dákẹ́, tí mo sì fà sẹ́yìn?*+ O ò wá bẹ̀rù mi rárá.