Sáàmù 100:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+ Àìsáyà 29:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí tó bá rí àwọn ọmọ rẹ̀,Tí wọ́n jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ mi, ní àárín rẹ̀,+Wọ́n máa sọ orúkọ mi di mímọ́;Àní, wọ́n máa sọ Ẹni Mímọ́ Jékọ́bù di mímọ́,Wọ́n sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run Ísírẹ́lì gidigidi.+
3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+
23 Torí tó bá rí àwọn ọmọ rẹ̀,Tí wọ́n jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ mi, ní àárín rẹ̀,+Wọ́n máa sọ orúkọ mi di mímọ́;Àní, wọ́n máa sọ Ẹni Mímọ́ Jékọ́bù di mímọ́,Wọ́n sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run Ísírẹ́lì gidigidi.+