Jeremáyà 51:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Nígbà tí ọ̀fun wọn bá ń dá tòló, màá se àsè fún wọn, màá sì rọ wọ́n yó,Kí wọ́n lè yọ̀;+Nígbà náà, wọ́n á sùn títí lọ,Tí wọn kò ní jí,”+ ni Jèhófà wí.
39 “Nígbà tí ọ̀fun wọn bá ń dá tòló, màá se àsè fún wọn, màá sì rọ wọ́n yó,Kí wọ́n lè yọ̀;+Nígbà náà, wọ́n á sùn títí lọ,Tí wọn kò ní jí,”+ ni Jèhófà wí.