Jeremáyà 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+ Jeremáyà 25:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Ẹ mu, kí ẹ sì yó, ẹ bì, kí ẹ sì ṣubú, tí ẹ kò fi ní lè dìde+ nítorí idà tí màá rán sáàárín yín.”’ Jeremáyà 51:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Màá mú kí àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn amòye rẹ̀ mutí yó,+Àwọn gómìnà rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn jagunjagun rẹ̀,Wọ́n á sì sùn títí lọ,Wọn ò sì ní jí,”+ ni Ọba wí, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.
27 “Kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Ẹ mu, kí ẹ sì yó, ẹ bì, kí ẹ sì ṣubú, tí ẹ kò fi ní lè dìde+ nítorí idà tí màá rán sáàárín yín.”’
57 Màá mú kí àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn amòye rẹ̀ mutí yó,+Àwọn gómìnà rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn jagunjagun rẹ̀,Wọ́n á sì sùn títí lọ,Wọn ò sì ní jí,”+ ni Ọba wí, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.