Àìsáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Àìsáyà 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+
16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+