Jeremáyà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ̀sùn wo ni àwọn baba ńlá yín fi kàn mí,+Tí wọ́n fi lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi,Tí wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ tí àwọn fúnra wọn sì di asán?+ Hósíà 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i pé ó gbéra ga,+Síbẹ̀ wọn kò pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wọn,+Bẹ́ẹ̀ ni wọn kò wá a pẹ̀lú adúrú ohun tí wọ́n ṣe yìí. Míkà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ẹ̀yin èèyàn mi, kí ni mo ṣe fún yín? Kí ni mo ṣe tí ọ̀rọ̀ mi fi sú yín?+ Ẹ sọ ohun tí mo ṣe.
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ̀sùn wo ni àwọn baba ńlá yín fi kàn mí,+Tí wọ́n fi lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi,Tí wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ tí àwọn fúnra wọn sì di asán?+
10 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i pé ó gbéra ga,+Síbẹ̀ wọn kò pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wọn,+Bẹ́ẹ̀ ni wọn kò wá a pẹ̀lú adúrú ohun tí wọ́n ṣe yìí.