Sáàmù 80:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 O mú kí àjàrà+ kan kúrò ní Íjíbítì. O lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde, o sì gbin àjàrà náà.+ Àìsáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+ Jeremáyà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+ Lúùkù 20:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ àpèjúwe yìí fún àwọn èèyàn pé: “Ọkùnrin kan gbin àjàrà,+ ó gbé e fún àwọn tó ń dáko, ó sì rìnrìn àjò lọ sí ilẹ̀ òkèèrè fúngbà díẹ̀.+
7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+
21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+
9 Lẹ́yìn náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ àpèjúwe yìí fún àwọn èèyàn pé: “Ọkùnrin kan gbin àjàrà,+ ó gbé e fún àwọn tó ń dáko, ó sì rìnrìn àjò lọ sí ilẹ̀ òkèèrè fúngbà díẹ̀.+