- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 15:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Ìwọ yóò mú wọn wá, ìwọ yóò sì gbìn wọ́n sí òkè ogún rẹ,+ Ibi tó fìdí múlẹ̀ tí o ti pèsè kí ìwọ fúnra rẹ lè máa gbé, Jèhófà, Ibi mímọ́ tí o fi ọwọ́ rẹ ṣe, Jèhófà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Àìsáyà 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ẹni tí mo fẹ́ràn ní ọgbà àjàrà kan síbi òkè tó lọ́ràá. 
 
-