ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá.

      O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+

      Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+

      Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.

  • Diutarónómì 33:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ó sì di ọba ní Jéṣúrúnì,*+

      Nígbà tí àwọn olórí àwọn èèyàn náà kóra jọ,+

      Pẹ̀lú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.+

  • Diutarónómì 33:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+

      Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,

      Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́