Diutarónómì 33:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó sì di ọba ní Jéṣúrúnì,*+Nígbà tí àwọn olórí àwọn èèyàn náà kóra jọ,+Pẹ̀lú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.+ Àìsáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+
22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+