Diutarónómì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ẹ̀yin fúnra yín ti rí nǹkan wọ̀nyí kí ẹ lè mọ̀ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́;+ kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan.+ Diutarónómì 4:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí, kí o sì fi sọ́kàn pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+ Kò sí ẹlòmíì.+ Àìsáyà 43:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+
35 Ẹ̀yin fúnra yín ti rí nǹkan wọ̀nyí kí ẹ lè mọ̀ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́;+ kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan.+
39 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí, kí o sì fi sọ́kàn pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+ Kò sí ẹlòmíì.+
10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+