ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 10:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ẹ lọ bá àwọn ọlọ́run tí ẹ yàn, kí ẹ sì ké pè wọ́n pé kí wọ́n ràn yín lọ́wọ́.+ Kí wọ́n gbà yín sílẹ̀ nígbà tí wàhálà dé bá yín.”+

  • 1 Àwọn Ọba 18:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Torí náà, wọ́n mú akọ ọmọ màlúù tí wọ́n yàn, wọ́n ṣètò rẹ̀, wọ́n sì ń pe orúkọ Báálì láti àárọ̀ títí di ọ̀sán, wọ́n ń sọ pé: “Báálì, dá wa lóhùn!” Ṣùgbọ́n wọn ò gbọ́ ohùn kankan, ẹnì kankan ò sì dá wọn lóhùn.+ Wọ́n sì ń tiro yí ká pẹpẹ tí wọ́n ṣe.

  • 1 Kọ́ríńtì 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́