Àìsáyà 42:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+ Àìsáyà 48:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọwọ́ mi ni mo fi fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Ọwọ́ ọ̀tún mi ni mo sì fi na ọ̀run.+ Tí mo bá pè wọ́n, wọ́n jọ máa dìde.
5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+
13 Ọwọ́ mi ni mo fi fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Ọwọ́ ọ̀tún mi ni mo sì fi na ọ̀run.+ Tí mo bá pè wọ́n, wọ́n jọ máa dìde.