ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 44:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ,+

      Ẹni tó dá ọ látìgbà tí o ti wà nínú oyún:

      “Èmi ni Jèhófà, ẹni tó dá ohun gbogbo.

      Èmi fúnra mi ni mo na ọ̀run,+

      Mo sì tẹ́ ilẹ̀ ayé.+

      Ta ló wà pẹ̀lú mi?

  • Jeremáyà 32:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Wò ó! Agbára ńlá rẹ+ àti apá rẹ tí o nà jáde lo fi dá ọ̀run àti ayé. Kò sí ohun tó ṣòroó ṣe fún ọ,

  • Sekaráyà 12:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ìkéde:

      “Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa Ísírẹ́lì,”

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà, Ẹni tó na ọ̀run jáde,+

      Tó fi ìpìlẹ̀ ayé lélẹ̀,+

      Tó sì dá ẹ̀mí* sínú èèyàn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́